Video Editing in Yoruba

Video Editing in Yoruba

Ninu aworan yi, a o fi hàn yin ona ti o yara lati ni imo eko bi a sele to aworan po (Video Editing) layi fi akoko seofo nipa lilo Adobe Premiere Pro ati Adobe After Effects.O le kọ nipa awọn ohun ìpìlẹ sise àtúnṣe aworan (video) ninu ẹkọ yi, ki o sí ni oyé ati iriri nipa titele awon itoni  ti a ti là kalẹ.O sì lè é tun ri awon itoni iranlọwọ miran lati fi kun oye rẹ nípa àwòrán (video) àti lílo àwọn ohun èlò inú rẹ lati ṣe awọn aworan ti o dara, ti o sì kún oju òṣùwọ̀n nipa lilo Adobe Premiere Pro ati Adobe After Effects.We have monthly LIVE question and answer sessions. Invitations to LIVE Q&A will be based on questions, while users can attend multiple sessions upon request.

(0 Ratings)

Report course

Please describe about the report short and clearly.

Share

Share course with your friends

Buy with points